Skip to main content

Posts

Showing posts from June, 2020

THE YOUTH PROVERBS (The prelim in Yoruba Language)

Ìbídámipé Oun gbogbo ti dojúrú tán bàyíí ní ìlú èdá, Eku kò, kó ké bí eku, Béè sìni eye kò kó ké bí eye móó, Oun gbogbo ti dòbírípo, Ìrònú dorí àgbà kodó, Sùgbón; ewo àwon èwe àti ìpéèrè bìi wón ti n yótòmì, Àfi bíi omo tí ìyá rè sèsè papò dà re bi àgbà nrè, Umn! Ótojú sú ni, nínú ìlú èdá, Kíni kí a se?  Àwon àgbàgbà ìlú foríkorí láti to elédùà lo, Elédùà seun, ònà àbáyo ti dé! Kí wá ni ònà àbáyo òún o? Ìbídámipè! Ìbídámipé ni ònà àbáyo. Tani ìbídámipé? Ìbídámipé ni; Àjòjì arewà aláboyún kan, Tí yiò wo inú ìlú Èdá wá láìròtélè, Tí ó ba tí leè bí omo inú rè sínú ìlú Èdá bàyí; ìlú yíò tùbà, yíò sì tùse,  Oun gbogbo yíò bòsípò fún gbogbo ènìà, Kòpé kòjìnà,  Arewà aláboyún kan wo inú ìlú wá, Ní pasè ìtóni amòye, Amò wípé arewà aláboyún yìí ni gbogbo ìlú ti nretí, Ní kété tí oùn yí balè, Gbogbo ará ìlú, terú tomo, tolórí telèmò, Tonílé tàlejò bá bèrè sí níí keé ìbídámipé bíi omo titun, Oba ìlú Èdá tilè fún ìbídámipé nì ilé nlá alárànbarà kan láti máa gbé, Nínú ilé ...

You Can Do It!

Who can CAN can CAN. yes! Who can't CAN can CAN. How? If you believe you can CAN,you will CAN. Believe in Yourself, you can CAN. If you can't CAN today, you can CAN tomorrow. Don't think because you can't CAN today, you can't CAN tomorrow. All you get to do is; believe in yourself that you will CAN. Someday! You will CAN. I mean soon!

THE YOUTH PROVERBS (The Prelim in Yoruba Language)

      Á n gbòròmodìe lówó ikú, Óní akò jé kí òun ràkìtàn lojè, Ló dífá fún ìwo òdó tí aso fún wípé; Òwúrò lojó eni bá máa ríre, Tí òún mí sínú wípé; Sèbí oòrùn tó wá lokè tóó sá aso gbe, Ìwo ti gbàgbé nì wípé; Eni bá kókó dójà ní máa kókó tà, Béè sìni ó dára láti sá aso gbe nì òwúrò Kí asì wòó ní òsán Jù kí asèsè máa fo aso ní òsán, àkókò òde, Oun gbogbo ni àkókò wà fùn, Ìgbà ara báàyí làá búra nítorí; Enìkan kìí bú sàngó nígbà èrùn, Nítorínà ìwo òdó, múra sísé owó re,  Sisé nígbàtí egungun re ní okun, Kí o má bàá fi ewú orí sisé nígbà tí ó báye kí o máa simi.